, ,

KIKO YORUBA NI AKOYE 2


3,800

Kiko Yoruba Akoye ni ilana eto eko kari-aye. Ede yoruba je okan pataki ninu awon ede abinibi ni agbaye. Ede yoruba, asa yoruba ati ihuwasi awon omo ile yoruba ti di ohun ti won  n ko ni orisirisi ile-eko giga kaakiri agbaye. America ni o, ile Geesi ni o, Russia ni o ati bee bee lo. Eni ti yoo si fun ni ni aso wo, ti orun re la koko wo naa.

 

Akowe:Qiògbón Adédejl Awóníyì, Alàgbà Lásún Adéwolé,  Alàgbà Lásúnkànmi Tệllà.

Vendor Information

  • Store Name: Buybooks
  • Vendor: Buybooks Bookshop
  • Address: Opposite Heritage Mall, 16 Obafemi Awolowo Way
    J. Allen, Dugbe
    Ibadan
    Oyo
  • No ratings found yet!