Ko sohun to buru ninu ka bi omo pupo, sugbon ohun to se koko ni ka se itoju won tori ojo ola. Nitori omo ti a bi ti a ko ko ni yoo gbe ile ti a ko ta. Morolagbe ati Alao ti o je iya ati baba fun Alake bi omo mejo. Aisi agbara lati se itoju awon omo wonyi lo mu ki won maa fi won losin kiri. Eyi lo mu Alake de odo Segilola ti o je ore Morolagbe iya Alake. Alake di eniti o n ta omi tutu ni garaaji.
Ki ni o gbeyin Alake? Ki ni o sele si awon obi Alake naa? E ka iwe yii ki e le mo idahun.
AUTHOR: Omolara Fadiya